Jump to content

Ẹranko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Animal)

Àwọn ẹranko
Animals
Temporal range: Ediacaran – Recent
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Àjákálẹ̀:
(unranked) Opisthokonta
(unranked) Holozoa
(unranked) Filozoa
Ìjọba:
Animalia

Phyla
Awon kiniun «Oba awon eranko»

Àwọn ẹranko je apa kan ninu awon ohun elemin alahamoarapupo ninu kingdom Eranko.

Awa ni awon ẹranko yàtọ̀, dàbí àwọn:

Okunrin pelu kẹtẹkẹtẹ lori ònà lati aaye

- kìnìún, awon ẹkùn, awon aláǹgbá, awon ejò, awon màlúù, awon àdàbà, awon òwìwí, àwọn aláǹtakùn, awon àgbọ̀nrín, kọlọkọlọ, awon amotèkun, awon kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà, ati awon ẹyẹ, àkùkọ, ìnàkí, àgùnfọn, Ọ̀bọ ( tabi aya) , Dainósò, Ẹyẹ pẹ́ngúìnì, edé ( tabi idé), aràn, amọtẹkun, Òfàfà, àgbọnrin, Ìjàpá, Awun òkun, ẹja, ekute, eku ti odò, Òfàfà ti Ìgbà òtútù, Akurakuda, Ótà òkun, irè (tabi antètè ), Kòkòrò lédíbọọ̀gì, idì, awodi, Ẹyẹ omi, Ẹja abániṣeré, Ẹja ẹléjò, Eṣinṣin, Aáyán, paramọlẹ, Dírágónì, Lámilámi, oyin, ọbọnbon, Ológbò, Ìgbín òkun, Ìgbìn, Ìkokò, Ìkokò àbàwọ́n , Adìyẹ, Àgùntàn, Kangaru, Ọ̀ọ̀nì, alegba, labalaba, Abo pẹ́pẹ́yẹ, pẹ́pẹ́yẹ, ayékòótó, erinmì, ọkẹrẹ (oforo) . Awa ni awon orisirisi ẹranko ni agbayé wa.

Awon Àmọ̀tẹ́kùn: Awon Àmọ̀tẹ́kùn saré kíákíá, ṣùgbọ́n, won ko le sáré fun àkókò ti ó pọ̀jù, ti won ba sâré, won ma saré fun àkóko kékeré nigba náà won ma nilo lati ni ìsinmi.

Awon Kiniun: Awa pe awon kiniun «<Ọba awon ẹranko» sugbon o le beere, «kini idi awa n pe won «Ọba awon Ẹranko» o ti béèré dáradára, idi ti awa n pe won «Ọba awon ẹranko» je nitori won je «Oba awon eranko» Awon kiniun, won le pariwo pelu ariwo ti o po gan ju gbogbo eranko ni igbo-kijikiji. Ti won ba pariwo, gbogbo eranko won ma saré fun igbesi aye won. Nitori, ko si eranko ni igbó ti o le se jagun pelu kiniun, ti won ba gbiyanju, won ma padanu gidigan. E ma duro pelu awon kiniun.

Àwọn ẹranko ti awa ni, ni gbogbo ayé poju ẹgbẹ̀rún ẹgbẹ̀rún méje ( àádọ́ta ọ̀kẹ́ méje )!![1]

{{reflist} eranko igbe

  1. https://www.wonderopolis.org/wonder/how-many-animals-are-there-in-the-world