Ẹ̀fúùfù
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Gas)
Kini Efuufu (Efufu) tabi afefe?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹfúùfù tabi efufu je nigba awon patiku afefe gbekuro, ati e ma mo pe o wa afefe tabi Efufu nigba e lero tabi fowokan ohun ti tutu tìntìn (dièdiè).
Kini Efufu Nla?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Efufu nla tumosi oruko tire. Efufu Nla je efufu ti nla gidigan. Efufu nla wa ewu gidigan, won ni agbara lati jabo ato yo kuro awon ilé ati ilé-iwé lati ilè.
Nibo mo nilo lati duro ni o wa Efufu Nla?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]E nilo lati duro ninu aja-ilè labè ilè.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |