Jump to content

Odídẹrẹ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Parrot)

Odídẹrẹ́
Temporal range: 54–0 Ma
Early Eocene[1] – Recent
Varied Lorikeet (Psitteuteles versicolor)
in Queensland, Australia.
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ẹyẹ (Aves)
Infraclass:
Ìtò:
Psittaciformes

Wagler, 1830
Ẹbí

Odídẹrẹ́ tabi Ẹyẹ ayékòótọ́ (parrot), awon ayékòótọ ni ebun, nitori pé won le soro, lootó, won le ba àwon èniyàn soro. Ko si eranko ti o le ba èniyàn soro, sugbon awon ayékòótọ́ le se. Ati won le tun-so ati tun-wi awon ohun ti awon èniyàn n so, o dara gidigan o!



  1. Waterhouse, David M. (2006). "Parrots in a nutshell: The fossil record of Psittaciformes (Aves)". Historical Biology 18 (2): 223–234. doi:10.1080/08912960600641224.