Jump to content

Archimedes

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Archimedes of Syracuse
(Greek: Ἀρχιμήδης)
Archimedes Thoughtful by Fetti (1620)
Ìbíc. 287 BC
Syracuse, Sicily
Magna Graecia
Aláìsíc. 212 BC
Syracuse
IbùgbéSyracuse, Sicily
Ẹ̀yàGreek
PápáMathematics, Physics, Engineering, Astronomy, Invention
Ó gbajúmọ̀ fúnArchimedes' Principle, Archimedes' screw, Hydrostatics, Levers, Infinitesimals

Tani ti je Archimedes?

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Archimedes ti Syracuse ti je okunrin ti o ti se «Eureka» nitori o ti je ninu iwẹ ati o ti iwari "fifo loju omi" ni èdè Geesi awa n pe e «buoyancy.»[1] Ohun yii, awa n pe "Ipilẹ-oye ti Archimedes" tabi awa n le so "Ofin ti Archimedes." Nigba ti Archimedes ti wa ri ohun yii, o ti se ohun itiju, o ti fo ita iwe ati o ti sáré lori òpópónà ihoho. Ohun ti awa fe so je pé, o ti sáré lori òpópónà laisi aṣo re! Nigba naa o ti bere lati kigbe ati ke "Eureka, eureka!" Tumo si je "Mo ti ri, mo ti ri" Archimedes ti se opolopo ilowosi ni imọ-jinlẹ ati ni mathimatiki tabi isiro.

Archimedes ti se àwọn iwari lori Pi ati lori roboto pèlú. O ti ri asopo pèlú agbegbe ati ìró ohùn ti roboto. [1]

Won ti bi Archimedes odun igba-ó-lé-metadinlaadorun saaju ti won ti bi Jesu, (287 BC). Archimedes ti je akeko ti mathimatiki, fisiksi, ati awòràwọ. Won ti bi Archimedes ni Syracuse, ileto Giriki ni orile-èdè Itali nigba àwọn omo-Romu ti gbogun si orile-èdè re. Nigba Hieron, ọba meji ti gbà agbara, o ti sofun alagbẹdẹ wúrà lati se ade wura fun o. Nigba naa, nigba ti ọba Hieron ti gbà ade, o ti nifura o ti ro pé alagbẹdẹ wúrà ti tan òun je. Ọba ti ro pé alagbẹdẹ wúrà ti dapọ fadaka pèlú wura nitori pé alagbẹdẹ wúrà o le pamo ati toju wura wura ajeku tabi wura ti ko ti lo lati se ade fun ọba. Ọba ko le danwo tabi fihan pé alagbẹdẹ wúrà ti se be. Nitori naa, o ti bere Archimedes lati se idanwo. Sugbon, o ti wi fun o pé ko le baje ade wura. Archimedes ti sofun ọba lati fun o ojo die-die lati ro. Leyin naa, Archimedes ti je ninu iwe ati o ronu nipa wahala ti o ni ati oran ti o soro. Nigba naa, Archimedes ti ri pé, nigba ti o ti wole ninu iwe, omi ti goke ati o ti kuro lati iwe ati lori ilẹ. Nigba ti o ti fi ara re ti o poju ni iwe, omi ti o poju ti goke ati kuro lati iwe, o ti ri pé o ti se rudurudu. Nigba naa, Archimedes ti ye pé o je asopo pelu melo ni omi ti kuro ati iwon ti ara mi. [1]

Leyin naa, Archimedes ti se awon adanwo pelu omi ati ade lati ri ti adé ba je adé gidigidi. Archimedes ti mo pé ipon ati iwuwo ti wura poju ipon ti fadaka. Ohun yii je pé, ti alagbẹdẹ wura ti dapọ wura ati fadaka ni adé ti ọba nipo lati se ohun ti ọba ti sofun lati se adé ti wura nikan, omi ti o ma kuro, o ma je yato. Leyin naa Archimedes ti fi adé ninu omi, ati o ti ri pé nigba ti o ti fi e ninu omi, omi ti o ti kuro lati omi ti poju ti omi ti o ti kuro nigba ti o ti fi wura ninu omi. Won ko ti je kanna, nitori naa, Archemides to mo pé alagbẹdẹ wura ti tan ọba jẹ .[1]