Before Common Era
Ìrísí
Kini BCE?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]BCE ati BC je kanna sùgbon, awon èniyàn ti ko gbiàgbo ninu Jesu Kristi tabi Oluwa-Olorun, won ma n lo BCE dipo BC. BCE tumo si èdè Geesi (English) je «Before The Common Era» sùgbon itumo ni èdè Yoruba je, «Saaju Asiko Wopo» tabi «Tele Asiko Wopo».