Jump to content

Common Era

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

CE ati AD je kanna, sùgbon awon èniyan ti ko gbàgbo ninu Jesu Kristi tabi Olorun, won n lo CE dipo AD. NI èdè Geesi (English) CE tumo si «Common Era» itumo ni èdè Yoruba je Asiko Wopo.