Google Translate
Ìrísí
Kini Google Translate? Tabi Itumo Google?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Google Translate je oye atowoda ti awon eniyan n lo lati ko ati se itumo lati ede kan si ede miiran. Google Translate le se itumo fun opolopo ede, Yoruba paapaa pelu!