Isedale
Ìrísí

Isedale (biology), je nigba awa kó ati kawé nipa awon eranko, iyè, ati ohun ti je laaye ninu gbogbo ayé.
Ikawe ti isedale je gbooro ati nla, nitori o je orisirisi eranko ati ìyè ninu agbayé wa. Awa le se ati da awon egbẹ lori àwọn ìyè ati iru ti ẹranko ti awa kawé.[1]

Ni isedale, awa n kó nipa ara ti èniyàn. Awa n kó nipa bawo apakan orisirisi ti èniyàn o n sise. Awa n kó nipa ounje ati nigba awa n jeun, bawo ounje lo ni ara wa ati ran wa lowo lati ni agbara, lati sise, lati seré ati ronu.
Ni isedale awa n kó nipa: Lilo Agbara Itansan Oorun (photosynthesis), [2] kabonu, nítrójínì, mitosis ati meiosis, ati orisirisi ohun.