Sáyẹ́nsì

Kini-Ìmọ jinlẹ (Sáyẹ́nsì)?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kini ìmọ-jinle tabi Sayensi? Imo-Jinle tabi Sayensi je nigba awa gbiyanju lati ye, kékò, ati kawe awon ohun ti Olorun ti da. Ni imo-jinlẹ, lati ni awon alamo, idamoran ohun, alaye, ati awon ofin se pataki gidigan. Ti awa n ko mo kankan, awa nilo lati kawe, ṣe akiyesi, kojo ati gba alaye lori ohun se pataki. Pelu alaye yii, awa n le gba imo ti o da. Imo-jinlẹ ran wa lowo lati mo dada ona ti Olorun ti da gbogbo ayé ati fun o ogo ni ipari nitori Olorun je nla ati o je ọba ti ayé.[1]



Ni imo-jinle awa ni fisiki, kemistri, ati isedale, isedale je ikawe nipa ohun ti wa laaye.
Imo-jinle ti ran wa lowo lati se orisirisi ohun. Pelu imo-jinle, awa ti kọ́ awon ọkọ̀ òfurufú, o ti soro sugbon awa ti se e. Pèlú imọ-jinlẹ awa ti kọ́ awon ọkọ oju omi akókó ati awa ti ye "fifo loju omi". Pelu imo-jinle awa ti kọ́ imo ẹrọ dabi ohun ti e n lo nissi lati ka nipa imo-jinle. Imo-jinle ti ran wa lowo ni ona orisirisi.
Awon ọkọ ofurufu akókò da, o wa ti da ni 1903 nipa Wilbur ati Orville Wright, awa pe ọkọ ofurufu «The Wright Flyer» ni ede Yoruba awa n pe «ohun ti n fo nipa Wright» Ohun ti n fo, ti fo ni Ojo 17, Osu kejila, 1903, ni Kitty Hawk, Carolina Ariwa
Awon akeko imo-jinle ti o tobi gan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Faraday
Alàgbà Isaac Newton
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Alàgbà Isaac Newton ti je okunrin ọlọgbọn gidigidi. Alàgbà Isaac Newton ti da fisiksi ati calculus nipa ara re nikan! Oga ti ile-ijosin ti so pé ni asiko ti iku ti Alàgbà Newton pé "Iseda ati ofin ti iseda ti dubule pamo ninu ale, Olúwa-Ọlọrun ti so pe, e je ki Newton je láàyè! Ati ohun gbogbo ti wa sinu imolẹ."[2]
Awon ohun ti o poju lori imọ-jinlẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Imọ-jinlẹ se pataki, imọ-jinlẹ ti ran wa lowo lati ye ayé wa dada. Pèlú imọ ti imọ-jinlẹ, awa ti da awon ẹrọ-imutobi, pèlú àwọn ẹrọ-imutobi awa n lé ri ita agbayé wa. Ni tele tele, won ti ro pé agbaye wa je roboto, ati won ti ro pé agbayé wa je arin ti gbogbo ayé. Súgbon nisinsin awa mo pé, ayé wa ko wa ni arin ti gbogbo. Ni otitó, orun je ni arin ti gbogbo ayé. Awa ni orisirisi irawo ti o ma yika orun. Awa n pe won: "Canis Minor," "Canis Major," "Orion," ati awon irawo miiran. Pèlú àwọn ẹrọ-imutobi, awa le ri awon ohun ti o poju.
Imọ-jinlẹ ni eka iwosàn ati oogun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Imọ-jinlẹ ti ran àwọn oniṣegun ati dokita lowo lati mu àwọn èniyàn larada. Àwọn èniyàn ti o ti ni pox-kékeré (smallpox), àwọn àkóràn ti o le pa àwọn èniyàn, akàn, ati orisirisi arun ati aisan. Bee ni, awa fun ogo si Olorun fun oye ati imọ ti o ti fun wa. Imọ-jinlẹ se pataki gidigan fun awon èniyàn ti o sise ni iwosàn, mo n so nipa awon oniṣegun ati dokita. Ti e ba fe di oniṣegun ati doita o nilo lati ni oyẹ ijinle ti sayensi ati imọ-jinlẹ.
Awon akọle ti o se pataki gidigan ni imo-jinle
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Walẹ
- DNA
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |